Play Open

GÓMÌNÀ OYÈBÁNJÍ TI KÍ GBOGBO ONÍLÉ ÀTÀLEJÒ L’ÉKÌTÌ KÚ ỌDÚN ÀJÍNDE

Gómìnà Èkìtì, Ọ̀gbẹ́ni Bíọ́dún Oyèbánjí ti kí gbogbo Krìstíánì lónílé àtàlejò kú ọdún Àjínde Jésù Krístì Olúwa wa.

Bẹ́ẹ̀ ló képè wọ́n láti wo ìfẹ́ tí Krístì fihàn nípa fífi ẹ̀mí rẹ̀ lélẹ̀ fún ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ aráyé, káwọn náà pẹ̀lú ní ìfẹ́ sí ọmọnìkéjì wa fún ìdàgbàsókè ìlú àtorílẹ̀ èdè.

Posted in Uncategorized
Previous
All posts
Next

Write a comment

Ministry of
Information

The official Website, Office of Ekiti State Ministry of Information

Contact Us

+234 8160768195

© 2023 EKSG – Ministry of Information . All Rights Reserved.